Ìrèké-Oníbùdó Quotes

Rate this book
Clear rating
Ìrèké-Oníbùdó Ìrèké-Oníbùdó by D.O. Fagunwa
78 ratings, 4.26 average rating, 10 reviews
Ìrèké-Oníbùdó Quotes Showing 1-2 of 2
“Arogidigba ni eyini. Ko tile jo eja rara, ó dabi
omobinrin ó sì di irun ori rẹ̀ winnikin ó da asọ àrán tí àwò rẹ̀ dàbí aṣo aláró tí wón sèsè rẹ bora, wón sì fi àrán pupa bo ẹ̀gbé ogiri léyìn rẹ̀, àtègùn kéékèèkéé kan báyìí ni wón fi òkúta se láti ìsàlẹ̀ lọ dé òkè ibi tí Àrògidigbà wà, gbogbo àyíká ibẹ̀ sì ní ẹwà gidigidi.
"Nígbà tí ó rí wa ó dide, igbà tí ó sì dide yìí ni mo tóó wáá rí i pé irù wà ní idi rè bii ti ẹja.”
D.O. Fagunwa, Ìrèké-Oníbùdó
“ELÉYÌÍ NI ÀÀFIN ÀRÒGÌDÌGBÀ TÍ Í SE OLÓRÍ ẸJA INÚ OMI, ỌDÚN ÀRỌ̀GÌDÌGBÀ SÚNMÓ ETÍLÉ KÍ ÀWỌN EBỌRA ÌSÀLÈ IBÚ OMI ÒKUN LỌ MÁA WÁ ÀWỌN ỌMỌ ÈNÌYÀN WÁ KÍ WÓN FI SE ÀRÍYÁ ỌDÚN ỌBA'.”
D.O. Fagunwa, Ìrèké-Oníbùdó